Daniẹli 2:31 BIBELI MIMỌ (BM)

“Kabiyesi, o rí ère kan níwájú rẹ ní ojúran, ère yìí tóbi gan-an, ó mọ́lẹ̀, ó ń dán, ìrísí rẹ̀ sì bani lẹ́rù.

Daniẹli 2

Daniẹli 2:21-38