Daniẹli 2:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun bá fi àṣírí náà han Daniẹli ní ojúran, lóru. Ó sì yin Ọlọrun ọ̀run lógo.

Daniẹli 2

Daniẹli 2:13-21