Daniẹli 12:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo gbọ́ tí ó ń sọ̀rọ̀, ṣugbọn ohun tí ń sọ kò yé mi. Mo bá bèèrè pé, “Olúwa mi, níbo ni nǹkan wọnyi yóo yọrí sí?”

Daniẹli 12

Daniẹli 12:6-13