Daniẹli 12:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọlọ́gbọ́n yóo máa tàn bí ìmọ́lẹ̀ ojú ọ̀run, àwọn tí wọn ń yí eniyan pada sí ọ̀nà òdodo yóo máa tàn bí ìràwọ̀ lae ati títí lae.”

Daniẹli 12

Daniẹli 12:1-11