Daniẹli 12:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Láti ìgbà tí wọn yóo mú ẹbọ ojoojumọ kúrò, tí wọn yóo gbé ohun ìríra sí ibi mímọ́, yóo jẹ́ eedegbeje ọjọ́ ó dín ọjọ́ mẹ́wàá (1,290).

Daniẹli 12

Daniẹli 12:1-13