Daniẹli 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọba Ijipti ní ìhà gúsù yóo lágbára, ṣugbọn ọ̀kan ninu àwọn ìjòyè rẹ̀ yóo lágbára jù ú lọ, ìjọba rẹ̀ yóo sì tóbi ju ti ọba lọ.

Daniẹli 11

Daniẹli 11:2-15