Daniẹli 11:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn tí wọ́n ń bá a jẹ oúnjẹ àdídùn pọ̀ gan-an ni yóo dìtẹ̀ mọ́ ọn; gbogbo ogun rẹ̀ ni yóo túká, ọpọlọpọ yóo sì kú.

Daniẹli 11

Daniẹli 11:19-28