Daniẹli 11:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo pada sí ìlú olódi ti ara rẹ̀, ṣugbọn ijamba yóo ṣe é, yóo sì ṣubú lójú ogun; yóo sì fi bẹ́ẹ̀ parẹ́ patapata.

Daniẹli 11

Daniẹli 11:10-27