Daniẹli 10:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí mo ti gbójú sókè, mo rí ọkunrin kan tí ó wọ aṣọ funfun, ó fi àmùrè wúrà ṣe ìgbànú.

Daniẹli 10

Daniẹli 10:1-8