Daniẹli 1:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọdún kẹta ìjọba Jehoiakimu ọba Juda, Nebukadinesari ọba Babiloni wá gbógun ti Jerusalẹmu, ó sì dótì í.

Daniẹli 1

Daniẹli 1:1-8