Àwọn Ọba Kinni 9:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Hiramu ọba fi àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n mọ̀ nípa ọkọ̀ ojú omi, lé àwọn ọkọ̀ náà, ó kó wọn rán àwọn iranṣẹ Solomoni sí i.

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:17-28