Àwọn Ọba Kinni 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó yá, ọmọ ọba Farao, iyawo Solomoni kó kúrò ní ìlú Dafidi, ó lọ sí ilé tí Solomoni kọ́ fún un. Lẹ́yìn náà ni Solomoni kọ́ ìlú Milo.

Àwọn Ọba Kinni 9

Àwọn Ọba Kinni 9:16-26