Àwọn Ọba Kinni 8:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò sí ohunkohun ninu Àpótí Ẹ̀rí náà, àfi tabili òkúta meji tí Mose kó sinu rẹ̀ ní òkè Sinai, níbi tí OLUWA ti bá àwọn ọmọ Israẹli dá majẹmu, nígbà tí wọn ń ti Ijipti bọ̀.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:8-19