Àwọn Ọba Kinni 8:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Solomoni fi ọ̀kẹ́ kan ati ẹgbaa (22,000) mààlúù, ati ọ̀kẹ́ mẹfa (120,000) aguntan rú ẹbọ alaafia sí OLUWA. Bẹ́ẹ̀ ni òun ati àwọn ọmọ Israẹli ṣe ya ilé OLUWA náà sí mímọ́.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:58-66