Àwọn Ọba Kinni 8:56 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ìyìn ni fún OLUWA, tí ó fún àwọn eniyan rẹ̀ ní ìsinmi gẹ́gẹ́ bí ìlérí rẹ̀. Ó ti mú gbogbo ìlérí rere rẹ̀ tí ó ṣe láti ẹnu Mose, iranṣẹ rẹ̀, ṣẹ.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:46-61