Àwọn Ọba Kinni 8:44 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí àwọn eniyan rẹ bá lọ dojú kọ àwọn ọ̀tá wọn lójú ogun, níbikíbi tí o bá rán wọn lọ, tí wọ́n bá kọjú sí ìlú tí o yàn yìí, ati ilé ìsìn tí mo kọ́ fún ọ, tí wọ́n sì gbadura,

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:42-52