Àwọn Ọba Kinni 8:35 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí o kò bá jẹ́ kí òjò rọ̀, nítorí pé wọ́n ṣẹ̀ ọ́, tí wọ́n bá ronupiwada tí wọ́n sì kọjú sí ilé ìsìn yìí, tí wọ́n gbadura sí ọ, nígbà tí o bá jẹ wọ́n níyà,

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:27-44