Àwọn Ọba Kinni 8:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ṣugbọn, ǹjẹ́ ìwọ Ọlọrun lè gbé inú ayé yìí? Nítorí pé bí gbogbo ọ̀run ti tóbi tó, kò gbà ọ́; kí á má ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ ti ilé ìsìn tí mo kọ́ fún ọ?

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:18-29