Àwọn Ọba Kinni 8:20 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nisinsinyii OLUWA ti mú ìlérí rẹ̀ ṣẹ: mo ti gorí oyè lẹ́yìn Dafidi, baba mi, mo ti jọba ní ilẹ̀ Israẹli bí OLUWA ti ṣèlérí; mo sì ti kọ́ ilé fún OLUWA Ọlọrun Israẹli.

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:14-29