Àwọn Ọba Kinni 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Ìyìn ni fún OLUWA Ọlọrun Israẹli, tí ó mú ìlérí tí ó ṣe fún Dafidi, baba mi, ṣẹ, tí ó ní,

Àwọn Ọba Kinni 8

Àwọn Ọba Kinni 8:7-25