Àwọn Ọba Kinni 7:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ ilé tí òun alára óo máa gbé sí àgbàlá tí ó wà lẹ́yìn gbọ̀ngàn bí ó ti kọ́ àwọn ilé yòókù; ó sì kọ́ irú gbọ̀ngàn yìí gan-an fún ọmọ ọba Farao tí ó gbé ní iyawo.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:2-10