Àwọn Ọba Kinni 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó kọ́ gbọ̀ngàn kan tí ó sọ ní gbọ̀ngàn Olópòó. Gígùn rẹ̀ jẹ́ aadọta igbọnwọ, ìbú rẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n igbọnwọ. Ó ní ìloro kan tí wọ́n kọ́ sórí òpó; wọ́n ta nǹkan bò ó lórí.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:2-7