Àwọn Ọba Kinni 7:40 BIBELI MIMỌ (BM)

Huramu mọ ọpọlọpọ ìkòkò, ó fi irin rọ ọkọ́ pupọ, ó sì ṣe àwọn àwo kòtò. Bẹ́ẹ̀ ni ó ṣe parí iṣẹ́ tí ó bá Solomoni ọba ṣe ninu ilé OLUWA.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:38-48