Àwọn Ọba Kinni 7:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ṣe àwọn àgbá kẹ̀kẹ́ yìí bíi ti kẹ̀kẹ́ ogun, dídà ni wọ́n dà á ati irin tí àgbá náà fi ń yí, ati riimu wọn, ati sipoku ati họọbu wọn.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:25-34