Àwọn Ọba Kinni 7:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n to àwọn òpó, tí wọ́n kọ́ ilé yìí lé lórí, ní ìlà mẹta. Òpó mẹẹdogun mẹẹdogun wà ní ìlà kọ̀ọ̀kan. Wọ́n wá na ìtì igi kedari lé àwọn òpó náà lórí.

Àwọn Ọba Kinni 7

Àwọn Ọba Kinni 7:2-4