Àwọn Ọba Kinni 6:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n gbẹ́ igi ọ̀pẹ, ati òdòdó, ati àwọn kerubu sí ara àwọn ìlẹ̀kùn náà, wọ́n sì fi wúrà bo gbogbo wọn.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:28-38