Àwọn Ọba Kinni 6:32 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n gbẹ́ igi ọ̀pẹ, ati òdòdó, ati kerubu sí ara àwọn ìlẹ̀kùn náà; wọ́n sì yọ́ wúrà bò wọ́n patapata: ati igi ọ̀pẹ, ati òdòdó, ati àwọn Kerubu náà.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:25-37