Àwọn Ọba Kinni 6:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Gígùn ìyẹ́ mejeeji Kerubu keji náà jẹ́ igbọnwọ mẹ́wàá. Bákan náà ni àwọn Kerubu mejeeji yìí rí, bákan náà sì ni títóbi wọn.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:21-27