Àwọn Ọba Kinni 6:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojúlówó wúrà ni Solomoni fi bo gbogbo inú ilé ìsìn náà, wọ́n sì so ẹ̀wọ̀n kan, ó fi dábùú ẹnu ọ̀nà ibi mímọ́ ti inú, ó sì yọ́ wúrà bò ó.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:20-25