Àwọn Ọba Kinni 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Gígùn ilé tí Solomoni kọ́ fún OLUWA jẹ́ ọgọta igbọnwọ, ìbú rẹ̀ jẹ́ ogún igbọnwọ, gíga rẹ̀ sì jẹ́ ọgbọ̀n igbọnwọ.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:1-12