Àwọn Ọba Kinni 6:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ara ògiri ilé ìsìn náà níta ni wọ́n kọ́ ilé alágbèékà mẹta yìí mọ́, àgbékà kọ̀ọ̀kan ga ní igbọnwọ marun-un, wọ́n sì fi pákó igi kedari so wọ́n pọ̀ mọ́ ara ilé ìsìn náà.

Àwọn Ọba Kinni 6

Àwọn Ọba Kinni 6:1-17