Àwọn Ọba Kinni 5:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Gẹ́gẹ́ bí àṣẹ Solomoni ọba, wọ́n fọ́ òkúta ńláńlá, wọ́n sì gbẹ́ wọn fún mímọ ìpìlẹ̀ ilé OLUWA náà.

Àwọn Ọba Kinni 5

Àwọn Ọba Kinni 5:11-18