Àwọn Ọba Kinni 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ahiṣari ni olùdarí gbogbo àwọn tí ń ṣiṣẹ́ ninu ààfin. Adoniramu ọmọ Abida ni olórí àwọn tí ń kó àwọn eniyan ṣiṣẹ́ tipátipá.

Àwọn Ọba Kinni 4

Àwọn Ọba Kinni 4:4-7