Àwọn Ọba Kinni 4:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní gbogbo àkókò Solomoni, gbogbo àwọn ọmọ Juda ati àwọn ọmọ Israẹli wà ní alaafia láti ìlú Dani títí dé Beeriṣeba. Ìdílé kọ̀ọ̀kan ní ọgbà àjàrà ati àwọn igi ọ̀pọ̀tọ́ tirẹ̀.

Àwọn Ọba Kinni 4

Àwọn Ọba Kinni 4:21-32