Àwọn Ọba Kinni 4:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn nǹkan tí Solomoni ń lò fún ìtọ́jú oúnjẹ ní ọjọ́ kọ̀ọ̀kan nìwọ̀nyí: Ọgbọ̀n òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun tí ó kúnná dáradára, ati ọgọta òṣùnwọ̀n ọkà tí wọ́n lọ̀;

Àwọn Ọba Kinni 4

Àwọn Ọba Kinni 4:18-30