Àwọn Ọba Kinni 4:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Baana, ọmọ Ahiludi, ni alákòóso ìlú Taanaki, ati ti Megido, ati gbogbo agbègbè Beti Ṣeani, lẹ́bàá ìlú Saretani, ní ìhà gúsù Jesireeli ati Beti Ṣeani; títí dé ìlú Abeli Mehola títí dé òdìkejì Jokimeamu.

Àwọn Ọba Kinni 4

Àwọn Ọba Kinni 4:9-19