Àwọn Ọba Kinni 3:8 BIBELI MIMỌ (BM)

O sì fi èmi iranṣẹ rẹ sí ààrin àwọn eniyan tí o ti yàn fún ara rẹ, àwọn tí wọ́n pọ̀, tóbẹ́ẹ̀ tí wọn kò lóǹkà.

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:1-12