Àwọn Ọba Kinni 3:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba dáhùn, ó ní, “Ẹ má pa ààyè ọmọ yìí rárá, ẹ gbé e fún obinrin àkọ́kọ́. Òun gan-an ni ìyá rẹ̀.”

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:26-28