Àwọn Ọba Kinni 3:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Oríṣìíríṣìí pẹpẹ ìrúbọ ni àwọn eniyan tẹ́ káàkiri, tí wọ́n sì ń rúbọ lórí wọn, nítorí wọn kò tí ì kọ́ ilé OLUWA nígbà náà.

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:1-8