Àwọn Ọba Kinni 3:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọjọ́ kẹta tí mo bí ọmọ tèmi ni obinrin yìí náà bí ọmọkunrin kan. Àwa meji péré ni a wà ninu ilé, kò sí ẹnìkẹta pẹlu wa.

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:14-25