Àwọn Ọba Kinni 3:13 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo fún ọ ní ohun tí o kò tilẹ̀ bèèrè. O óo ní ọrọ̀ ati ọlá tóbẹ́ẹ̀ tí kò ní sí ọba kan tí yóo dàbí rẹ ní gbogbo ọjọ́ ayé rẹ.

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:12-19