Àwọn Ọba Kinni 3:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun sì dá a lóhùn, ó ní, “Nítorí pé ọgbọ́n láti mọ ohun tí ó dára ni o bèèrè, tí o kò bèèrè ẹ̀mí gígùn, tabi ọpọlọpọ ọrọ̀ fún ara rẹ, tabi ẹ̀mí àwọn ọ̀tá rẹ,

Àwọn Ọba Kinni 3

Àwọn Ọba Kinni 3:3-12