Àwọn Ọba Kinni 22:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jehoṣafati bèèrè pé, “Ṣé kò tún sí wolii OLUWA mìíràn mọ́, tí a lè wádìí lọ́dọ̀ rẹ̀?”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:2-9