Àwọn Ọba Kinni 22:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Jehoṣafati fi ṣugbọn kan kún ọ̀rọ̀ rẹ̀ pé, “Jẹ́ kí a kọ́kọ́ wádìí lọ́wọ́ OLUWA ná.”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:1-6