Àwọn Ọba Kinni 22:45 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo nǹkan yòókù tí Jehoṣafati ṣe, gbogbo iṣẹ́ akikanju rẹ̀, ati gbogbo ogun tí ó jà, wà ninu àkọsílẹ̀ Ìwé Ìtàn Àwọn Ọba Juda.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:38-48