Àwọn Ọba Kinni 22:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí oòrùn ń lọ wọ̀, wọ́n kéde fún gbogbo àwọn ọmọ ogun pé, “Kí olukuluku pada sí agbègbè rẹ̀! Kí kaluku kọrí sí ìlú rẹ̀!”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:32-42