Àwọn Ọba Kinni 22:32 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, nígbà tí wọ́n rí Jehoṣafati ọba, wọ́n ní, “Dájúdájú ọba Israẹli nìyí.” Wọ́n bá yipada láti bá a jà; ṣugbọn Jehoṣafati kígbe.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:23-35