Àwọn Ọba Kinni 22:23 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nítorí náà, gbọ́ nisinsinyii, OLUWA ni ó jẹ́ kí àwọn wolii wọnyi máa purọ́ fún ọ, nítorí pé ó ti pinnu láti jẹ́ kí ibi bá ọ.”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:16-31