Àwọn Ọba Kinni 22:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ahabu tún bi í pé, “Ìgbà mélòó ni n óo sọ fún ọ pé, nígbà tí o bá sọ̀rọ̀ fún mi ní orúkọ OLUWA, kí o máa sọ òtítọ́ fún mi?”

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:9-26