Àwọn Ọba Kinni 22:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nǹkan kan náà ni gbogbo àwọn wolii yòókù ń wí, gbogbo wọn ní kí Ahabu lọ gbógun ti Ramoti Gileadi, wọ́n ní OLUWA yóo fún un ní ìṣẹ́gun.

Àwọn Ọba Kinni 22

Àwọn Ọba Kinni 22:10-13